1 Ọba 4:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gébérì ọmọ Úrì ní Gílíádì; orílẹ̀ èdè Ṣíhónì ọba àwọn ará Ámórì àti orílẹ̀ èdè Ógù ọba Básánì. Òun nìkan ni ìjòyè lórí ilẹ̀ náà.

1 Ọba 4

1 Ọba 4:14-28