1 Ọba 4:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Sólómónì ọba sì jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì.

2. Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè rẹ̀:Ásáríyà ọmọ Ṣádókù àlùfáà:

3. Élíhóréfù àti Áhíjà àwọn ọmọ Ṣísánì akọ̀wé;Jèhósáfátì ọmọ Áhílúdì ni akọ̀wé ìlú;

1 Ọba 4