1 Ọba 3:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì pàṣẹ pé: “Ẹ gé alààyè ọmọ sí méjì, kí ẹ sì mú ìdajì fún ọ̀kan, àti ìdajì fún èkejì.”

1 Ọba 3

1 Ọba 3:23-26