1 Ọba 22:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níti ìyókù ìṣe Jèhósáfátì àti ìṣe agbára rẹ̀ tí ó ṣe, àti bí ó ti jagun sí, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba Júdà?

1 Ọba 22

1 Ọba 22:44-53