1 Ọba 22:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Árámù ti pàṣẹ fún àwọn olórí kẹ̀kẹ́ rẹ̀ méjìlélọ́gbọ̀n wí pé, “Ẹ má ṣe bá ẹnìkankan jà, ẹni kékeré tàbí ẹni ńlá, bí kò ṣe ọba Ísírẹ́lì nìkan.”

1 Ọba 22

1 Ọba 22:27-37