1 Ọba 22:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míkáyà sì wí pé, “Bí ìwọ bá padà bọ̀ ní àlàáfíà, Olúwa kò ti ipa mi sọ̀rọ̀.” Ó sì tún wí pé, “Ẹ kíyèsí ọ̀rọ̀ mi, ẹ̀yin ènìyàn gbogbo!”

1 Ọba 22

1 Ọba 22:24-29