1 Ọba 22:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣedekíà ọmọ Kénáánà sì ṣe ìwo irin fún ara rẹ̀, ó sì wí pé, “Báyìí ni Olúwa wí: ‘Wọ̀nyí ni ìwọ yóò fi kan àwọn ará Árámù títí ìwọ yóò fi run wọ́n.’ ”

1 Ọba 22

1 Ọba 22:2-21