1 Ọba 21:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésébélì aya rẹ̀ sì tọ̀ ọ́ wá, ó sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Èéṣe tí inú rẹ fi bàjẹ́, Èéṣe tí ìwọ kò sì jẹun?”

1 Ọba 21

1 Ọba 21:4-6