1 Ọba 21:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ̀kalẹ̀ lọ láti lọ pàdé Áhábù ọba Ísírẹ́lì, tí ó wà ní Samáríà. Ó wà ní ọgbà àjàrà Nábótì báyìí, níbi tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ láti jogún rẹ̀.

1 Ọba 21

1 Ọba 21:14-22