1 Ọba 20:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì náà sì lọ, ó sì dúró de ọba ní ojú ọ̀nà. Ó pa ara rẹ̀ dà ní fífi eérú bo ojú.

1 Ọba 20

1 Ọba 20:32-39