1 Ọba 20:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ọ̀rọ̀ Olúwa, ọkùnrin kan nínú àwọn ọmọ àwọn wòlíì sì wí fún èkejì rẹ̀ pé, “Jọ̀ ọ́, lù mí,” ṣùgbọ́n ó kọ̀ láti lù ú.

1 Ọba 20

1 Ọba 20:32-42