1 Ọba 20:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn Ọlọ́run kan sì gòkè wá, ó sì sọ fún ọba Ísírẹ́lì pé, “Báyìí ni Olúwa wí: ‘Nítorí tí àwọn ará Árámù rò pé Olúwa, Ọlọ́run òkè ni, ṣùgbọ́n òun kì í ṣe Ọlọ́run àfonífojì, nítorí náà èmi ó fi gbogbo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yìí lé ọ lọ́wọ́, ẹ̀yin yóò sì mọ̀ pé, Èmi ni Olúwa.’ ”

1 Ọba 20

1 Ọba 20:27-33