1 Ọba 20:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe ní àmọ́dún, Bẹni-Hádádì ka iye àwọn ará Árámù, ó sì gòkè lọ sí Áfékì, láti bá Ísírẹ́lì jagun.

1 Ọba 20

1 Ọba 20:20-33