1 Ọba 20:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nǹkan yìí ni kí o sì ṣe: Mú àwọn ọba kúrò, olúkúlùkù kúrò ní ipò rẹ̀, kí o sì fi olórí ogun sí ipò wọn.

1 Ọba 20

1 Ọba 20:16-31