1 Ọba 20:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí pé, “Bí wọ́n bá bá ti àlàáfíà jáde wá, ẹ mú wọn láàyè; bí ti ogun ni wọ́n bá bá jáde, ẹ mú wọn láàyè.”

1 Ọba 20

1 Ọba 20:16-26