1 Ọba 2:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì fi Bénáyà ọmọ Jéhóíádà jẹ olórí ogun ní ipò Jóábù àti Sádókù àlùfáà ní ipò Ábíátarì.

1 Ọba 2

1 Ọba 2:28-38