1 Ọba 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wàyìí, Àdóníjà ọmọ Hágítì tọ Bátíṣébà, ìyá Sólómónì wá. Bátíṣébà sì bi í pé, “Àlàáfíà ni o bá wa bí?”Ó sì dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, àlàáfíà ni.”

1 Ọba 2

1 Ọba 2:7-18