1 Ọba 18:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíjà sì dá a lóhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, lọ kí o sọ fún olúwa rẹ pé, ‘Èlíjà ń bẹ níhìn ín.’ ”

1 Ọba 18

1 Ọba 18:1-11