1 Ọba 18:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ó sì ṣe, lẹ́yìn ọjọ́ púpọ̀, ní ọdún kẹta, ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ Èlíjà wá pé: “Lọ, kí o sì fi ara rẹ̀ hàn fún Áhábù, èmi yóò sì rọ òjò sórí ilẹ̀.”

2. Bẹ́ẹ̀ ni Èlíjà lọ fi ara rẹ̀ han Áhábù.Ìyàn ńlá sì mú ní Samáríà,

1 Ọba 18