1 Ọba 16:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣímírì, ọ̀kan nínú àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, olórí ìdajì kẹ̀kẹ́ rẹ̀, dìtẹ̀ sí i. Élà sì wà ní Tírísà nígbà náà, ó sì mu àmupara ní ilé Árísà, ìríjú ilé rẹ̀ ni Tírísà.

1 Ọba 16

1 Ọba 16:5-11