1 Ọba 16:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ajá yóò jẹ ẹni Bááṣà tí ó bá kú ní ìlú, ẹyẹ ojú ọ̀run yóò sì jẹ àwọn tí ó kú ní oko.”

1 Ọba 16

1 Ọba 16:1-9