1 Ọba 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rìn nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí baba rẹ̀ ti dá ṣáájú rẹ̀; ọkàn rẹ̀ kò sì pé pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọkàn Dáfídì bàbáńlá rẹ̀ ti ṣe.

1 Ọba 15

1 Ọba 15:1-12