1 Ọba 15:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áṣà sì sùn pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ̀, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ̀ ní ìlú Dáfídì bàbá rẹ̀. Jèhóṣáfátì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

1 Ọba 15

1 Ọba 15:19-26