Réhóbóámù sì sùn pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ̀, a sì sin ín pẹ̀lú wọn ní Ìlú Dáfídì. Orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Náámá; ará Ámónì. Ábíjà ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.