1 Ọba 14:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdà sì ṣe búburú níwájú Olúwa nípa ẹ̀ṣẹ̀ wọn tí wọ́n ti dá, wọ́n sì mú u jowú ju gbogbo èyí tí baba wọn ti ṣe lọ.

1 Ọba 14

1 Ọba 14:21-30