1 Ọba 14:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nítorí èyí, Èmi yóò mú ibi wá sí ilé Jéróbóámù. Èmi yóò ké gbogbo ọ̀dọ́mọkùnrin kúrò lọ́dọ̀ Jéróbóámù, àti ọmọ ọ̀dọ̀ àti òmìnira ní Ísírẹ́lì. Èmi yóò mú ilé Jéróbóámù kúrò bí ènìyàn ti ń kó ìgbẹ́ kúrò, títí gbogbo rẹ̀ yóò fi tán.

1 Ọba 14

1 Ọba 14:7-14