1 Ọba 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́sẹ̀ kan náà, pẹpẹ ya, eérú náà sì dànù kúrò lórí pẹpẹ náà gẹ́gẹ́ bí àmì tí ènìyàn Ọlọ́run ti fi fún un nípa ọ̀rọ̀ Olúwa.

1 Ọba 13

1 Ọba 13:1-15