1 Ọba 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì àgbà kan wà tí ń gbé Bétélì, ẹni tí àwọn ọmọ rẹ̀ dé, tí ó sì ròyìn gbogbo ohun tí ènìyàn Ọlọ́run náà ti ṣe ní Béttélì ní ọjọ́ náà fún un. Wọ́n sì tún sọ fún baba wọn ohun tí ó sọ fún ọba.

1 Ọba 13

1 Ọba 13:8-15