1 Ọba 13:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì kíyèsii, ènìyàn Ọlọ́run kan wá láti Júdà sí Bétélì nípa ọ̀rọ̀ Olúwa, bì Jéróbóámù sì ti dúró lẹ́bàá a pẹpẹ láti fi tùràrí jóná.

1 Ọba 13

1 Ọba 13:1-10