1 Ọba 12:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Réhóbóámù ọba rán Ádórámù jáde, ẹni tí ń ṣe olórí iṣẹ́ irú, ṣùgbọ́n gbogbo Ísírẹ́lì sọ ọ́ ní òkúta pa, Réhóbóámù ọba, yára láti gun kẹ̀kẹ́ rẹ̀, ó sì sá lọ sí Jérúsálẹ́mù.

1 Ọba 12

1 Ọba 12:14-22