1 Ọba 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Baba mi ti gbé àjàgà wúwo lé e yín; Èmi yóò sì fi kún àjàgà yín. Baba mi ti fi pàsán nà yín; Èmi yóò fi àkéekèe nà yín.”

1 Ọba 12

1 Ọba 12:1-21