1 Ọba 11:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lórí òkè tí ń bẹ níwájú Jérúsálẹ́mù, Sólómónì kọ́ ibi gíga kan fún Kémósì, òrìṣà ìríra Móábù, àti fún Mólékì, òrìṣà ìríra àwọn ọmọ Ámónì.

1 Ọba 11

1 Ọba 11:1-14