1 Ọba 11:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò sì wí fún un pé, “Kí ni ìwọ ṣe aláìní níbí, tí ìwọ fi fẹ́ padà lọ sí ìlú rẹ?”Hádádì sì wí pé, “Kò sí nǹkan, ṣùgbọ́n sá à jẹ́ kí èmi kí ó lọ!”

1 Ọba 11

1 Ọba 11:13-29