1 Ọba 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni inú àwọn ènìyàn rẹ yóò ṣe dùn tó! Báwo ni inú dídùn àwọn ìránṣẹ́ rẹ, tí wọ́n ń dúró níwájú rẹ nígbà gbogbo, tí wọ́n sì ń gbọ́ ọgbọ́n rẹ!

1 Ọba 10

1 Ọba 10:4-15