1 Ọba 10:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì mú ẹṣin wá fún Sólómónì láti Éjíbítì ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́, oníṣòwò ọba ni ó ń mú wọn wá fún òwe.

1 Ọba 10

1 Ọba 10:25-29