1 Ọba 10:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì sì kó kẹ̀kẹ́ àti ẹṣin jọ; ó sì ní egbèje (1400) kẹ̀kẹ́ àti ẹgbàata (13,000) ẹlẹ́ṣin, tí ó fi pamọ́ sí ìlú kẹ̀kẹ́ àti pẹ̀lú rẹ̀ ní Jérúsálẹ́mù.

1 Ọba 10

1 Ọba 10:19-29