1 Ọba 10:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìtẹ́ náà sì ní àtẹ̀gùn mẹ́fà, èyín rẹ̀ sì ṣe róbótó lókè. Ní ibi ìjókòó méjèèjì náà ni irọpá wà, pẹ̀lú kìnnìún tí ó dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ ìkọ̀ọ̀kan wọn.

1 Ọba 10

1 Ọba 10:16-26