1 Ọba 10:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì ọba sì ṣe igba (200) aṣà wúrà lílù; ẹgbẹ̀ta (600) ṣékélì wúrà ni ó lọ sí asà kan.

1 Ọba 10

1 Ọba 10:10-26