1 Ọba 10:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì fi igi Álúgúmù náà ṣe òpó fún ilé Olúwa àti fún ààfin ọba, àti láti ṣe dùùrù pẹ̀lú àti ohun èlò orin mìíràn fún àwọn akọrin. Irú igi Álúgúmù bẹ́ẹ̀ kò dé mọ́, bẹ́ẹ̀ ni a kò rí wọn títí di òní yìí.

1 Ọba 10

1 Ọba 10:7-15