1 Ọba 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdóníjà sì gbérò pẹ̀lú Jóábù, ọmọ Ṣérúyà àti Ábíátarì àlùfáà, wọ́n sì ṣe ìrànlọ́wọ́ fún un.

1 Ọba 1

1 Ọba 1:4-17