1 Ọba 1:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì wí pé, ‘Ògo ni fún Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tí ó ti jẹ́ kí ojú mi rí ẹnìkan tí ó jókòó lórí ìtẹ́ mi lónìí.’ ”

1 Ọba 1

1 Ọba 1:39-50