1 Ọba 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọbìnrin náà rẹwà gidigidi; ó sì ń ṣe ìtọ́jú ọba, ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún un, ṣùgbọ́n ọba kò sì bá a lò pọ̀.

1 Ọba 1

1 Ọba 1:1-6