1 Ọba 1:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Bátíṣébà tẹriba, ó sì kúnlẹ̀ níwájú ọba pé, “Kí Olúwa mi Dáfídì ọba kí ó pẹ́!”

1 Ọba 1

1 Ọba 1:21-36