1 Ọba 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún ọba pé, “Olúwa mi; ìwọ fúnra rẹ fi Olúwa Ọlọ́run rẹ búra fún ìránṣẹ́ rẹ pé: ‘Sólómónì ọmọ rẹ yóò jọba lẹ́yìn mi, yóò sì jókòó lórí ìtẹ́ mi.’

1 Ọba 1

1 Ọba 1:7-27