1 Kọ́ríńtì 7:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wù mí kí olúkúlùkù dàbí èmi láìgbéyàwó, ṣùgbọ́n gbogbo ènìyàn kò le jẹ́ bákan náà, Ọlọ́run fún olúkúlùkù ènìyàn ní ẹ̀bún tírẹ̀, ọ̀kan bí irú èyi àti èkejì bí irú òmíràn.

1 Kọ́ríńtì 7

1 Kọ́ríńtì 7:1-13