1 Kọ́ríńtì 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ọkùnrin kí ó fi gbogbo ẹ̀tọ́ ìyàwó rẹ̀ fún ún, kí ìyàwó fi gbogbo ẹ̀tọ́ ọkọ fún ọkọ rẹ̀.

1 Kọ́ríńtì 7

1 Kọ́ríńtì 7:1-9