1 Kọ́ríńtì 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ohun gbogbo ní ó yẹ fún mi,” ṣùgbọ́n kì í ṣe ohun gbogbo ni ó ní èrè; “Ohun gbogbo ni ó yẹ fún mi,” ṣùgbọ́n èmi kì yóò jẹ́ kí a fi mi ṣe olórí ohunkóhun.

1 Kọ́ríńtì 6

1 Kọ́ríńtì 6:3-16