1 Kọ́ríńtì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tàbí àwọn olè, tàbí àwọn wọ̀bìà, tàbí àwọn ọ̀mútí, tàbí àwọn apẹ̀gàn, tàbí àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà ni yóò jogún ìjọba Ọlọ́run.

1 Kọ́ríńtì 6

1 Kọ́ríńtì 6:9-11