1 Kọ́ríńtì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í ṣe iṣẹ́ mi láti máa ṣe ìdájọ́ (àwọn aláìgbàgbọ́) àwọn tí wọn kò sí nínú ìjọ. Dájúdájú iṣẹ́ tiwa ni láti ṣe ìdájọ́ àti láti fi ọwọ́ líle mú àwọn tí ń bẹ nínú ìjọ.

1 Kọ́ríńtì 5

1 Kọ́ríńtì 5:8-13