1 Kọ́ríńtì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí a ń fi ọwọ́ ara wa ṣiṣẹ́, wọn ń gàn wa, àwa ń súre, wọn ń ṣe inúnibíni sí wa, àwa ń forítì i.

1 Kọ́ríńtì 4

1 Kọ́ríńtì 4:5-14